Ko si ohun ti ọkunrin le se, ti obinrin kankan ko le se, bẹẹ si ni ọmọ ti yoo ba jẹ asamu, kekere ni yoo ti maa jẹnu samu-samu. Bẹẹ ni ọrọ ri nipa awọn akọni ọmọdebinrin ileẹkọ girama kan nipinlẹ Ondo ...